Wake Up
Zlatan
paroles Zlatan Wake Up

Zlatan - Wake Up Lyrics & Traduction

Ayé ayé aye
Wọ
Emi Sọkalẹ wo
Ibile
Sọkalẹ
Kapachimerimeripako

Oya when I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gba débi
Kinto gbà débi
When I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gbà débi
Kinto gbà débi
Odọ yi gba debi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Lo yo mi oh yeahh
Odọ yi gba debi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lọ yo mi
kinto gba debi
Ah ah ah ah
Kúrò bẹ
Wọ

Them say love na one tin tin
Na so this year gon bintin
I travel nígbà hẹn ade mọ ni olówó
ti kpa ma fi àkara fún mẹ koko
Everyday lafin she adura
Fún Jésù oriwa kin àwa jẹ nepa wa ge ino wà
Showers of blessing le npe
Ojú tí kún fún ádùrá
And I want build this legacy for my family
Before I komot for house
I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbe lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ijeta nimoni ko dahun konde pick call mí
When I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny (ah)
Kindo gba debi

When I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gba debi
Kinto gba debi
When I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gba debi

Odọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
Lo yo mi
Odọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lo yo mi
kinto gba debi
Wọ èmi rẹ
Mo wà jẹ ẹni tó wà fresh

Emi re mo wa dẹni tó wà fresh
Wọ èmi èmi rẹ
Mo wà jẹ ẹni tó wà fres
Emi re mo wa dẹni tó wà fresh
Èmi rẹ imọlẹ ti olùwà gbọ gbọ fi lè
Mọn hussle fún Toronto oh
Nínú òtútù ni mọn kólé
Ki ra igbo fún
Mọn ti fresh telé telé woni ongberun
Awọn wọnyi la abo
And I want build this legacy for my family
Before I komot for house
I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbe lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ijeta nimoni ko dahun konde pick call mí

Odọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
Lo yo mi
kinto gba debi
Odọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
Lo yo mi
kinto gba debi


Paroles2Chansons dispose d’un accord de licence de paroles de chansons avec la Société des Editeurs et Auteurs de Musique (SEAM)