paroles Angélique Kidjo Ogbo

Angélique Kidjo - Ogbo Lyrics & Traduction

Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh

Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba
Itẹ rẹ o monlè kpélou wura
Oti wa ni shọ lowo Kiniun méji
Kiniun meji ti ko jéra o
N'tori agbara won foun yin l'okan bale
Kiniun meji ti ko jéra o
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba

Shugbọn ma gbagbé l'ayé, kpé ojo buruku kan owa
Igbati won ji janu oruka rè
Ànjọnú Sakhar lo fọ agbara rè
Ànjọnú Sakhar lo dji oro rè

Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Asho ti awon olowo
Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji

Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba

Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba
Tabili rè nin smaragdu
On simi lori ẹssẹ oniyèbiyè mẹrin
Kiniun meji ti ko jéra o
To fun yin ni agbara, okanbalé
Kiniun meji ti ko jéra o
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba

Shugbọn ma gbagbé l'ayé, kpé ojo buruku kan owa
Igbati won ji janu oruka rè
Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi talaka
Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi alagbé

Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Asho ti awon olowo
Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji

Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh, Oh, Oh, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oh

Paroles2Chansons dispose d’un accord de licence de paroles de chansons avec la Société des Editeurs et Auteurs de Musique (SEAM)