[Adekunle Gold]
All my ladies, formation
All my ladies, e jale
Form', form', forma'
[Adekunle Gold]
All my ladies formation, if you are sexy, go low, low (Low, low)
Fine bọbọ, wetin sup? If you want it, you lowo (Lowo)
Fuck with me, baby, don't let me go (Me go)
Stop it, don't call me, "Bro"
Ewo l'ewo sisi eko, baby, hello
She say, "Oh, my Lord
Talk is cheap, show me working"
Ah, ṣo n te button, ko le re body
[Adekunle Gold]
Ẹ pé money changer kò ṣe'wo
Electro-fuji ló fẹ́ jó
Palazzo we ṣe ẹ máa gbọ́
Bureau de change, Kwankwanso
Ẹ pé money changer kò ṣe'wo
Kosoko music ló fẹ́ jó
Palazzo we se ẹ máa gbo
Bureau de change, Kwankwanso
[Adekunle Gold]
Ayy, fi le bẹ (Ah, ah), jo wa be
Ẹ jẹ́ kó lọ bẹ, wọn fẹ́ mọ bí mo ṣe jẹ́
Ọmọ iya mi, no dey vex
Ẹ sọ fún kó stop, ṣe be? (Yeah)
Ọmọlọmọ wọn níbọ ló ti r'ọwọ náà?'
Ìṣẹ́ kékeré, owo nla nla (Nla, nla)
[Olamide]
Wọn lè wọn lè, wọn lè bá
(Dey with me) Wọn lè bá
[Olamide]
Million, million dollar, ló na dollar
No be small, small, dollar
No be young young dollar, tan na dollar, awọn young dollar
Three comma, comma, lo gbe comma, owo Otedola
Stay close to me, my baby, U.I. gate to Mokola
Olólùfẹ́ mi baby (Uh), ìwọ ṣà má ready (Uh)
Whenever you ready (Uh), kí ìwọ ṣà ti pè mí (Uh)
Anything to ba fẹ, bó jo ku lo o láàlé
To ba ja cover ló fẹ́, ma ṣa nà sí lẹ labe, labe, labe
[Adekunle Gold, Olamide]
Ẹ pé money changer kò ṣe'wo
Electro-fuji ló ń fẹ́ jó
Palazzo we ṣe ẹ máa gbọ́
Bureau de change, Kwankwanso
Ẹ pé money changer kò ṣe'wo (Ẹ̀ pé money changer)
Kosoko music ló ń fẹ́ jó (Oh, money spender)
Palazzo we ṣe ẹ máa gbo (Baby, ta la so)
Bureau de , Kwankwanso
[Adekunle Gold]
Ayy, fi le bẹ (Ah, ah), jo wa be
Ẹ jẹ́ kó lọ bẹ, wọn fẹ́ mọ bí mo ṣe jẹ́
Ọmọ iya mi, no dey vex
Ẹ sọ fún kó stop, ṣe be? (Yeah)
Ọmọlọmọ wọn níbọ ló ti r'ọwọ náà?'
Ìṣẹ́ kékeré, owo nla nla (Nla, nla)
Paroles2Chansons dispose d’un accord de licence de paroles de chansons avec la Société des Editeurs et Auteurs de Musique (SEAM)